Jẹnẹsisi 41:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn meje tí wọ́n rù hangangan náà ki àwọn meje tí wọ́n sanra rọ̀pọ̀tọ̀ rọ̀pọ̀tọ̀ mọ́lẹ̀, wọ́n sì gbé wọn mì, Farao bá tají.

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:3-12