Jẹnẹsisi 41:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Oúnjẹ yìí ni àwọn eniyan yóo máa jẹ láàrin ọdún meje tí ìyàn yóo mú ní ilẹ̀ Ijipti, kí ilẹ̀ náà má baà parun ní àkókò ìyàn náà.”

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:35-37