Jẹnẹsisi 41:33 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ọ̀rọ̀ ti rí yìí, ó yẹ kí kabiyesi yan ọkunrin kan tí ó gbọ́n, tí ó sì lóye, kí ó fi ṣe olórí ní ilẹ̀ Ijipti.

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:31-41