Jẹnẹsisi 41:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn mààlúù meje mìíràn tún jáde láti inú odò náà, gbogbo wọn rù hangangan, wọ́n rí jàpàlà jàpàlà, n kò rí irú rẹ̀ rí ní gbogbo ilẹ̀ Ijipti.

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:13-23