Jẹnẹsisi 4:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá, Kaini pe Abeli lọ sinu oko. Nígbà tí wọ́n wà níbẹ̀, Kaini dìde sí Abeli àbúrò rẹ̀, ó sì lù ú pa.

Jẹnẹsisi 4

Jẹnẹsisi 4:1-9