Jẹnẹsisi 4:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Sila bí Tubali Kaini. Tubali Kaini yìí ni baba ńlá gbogbo àwọn alágbẹ̀dẹ tí ń rọ ohun èlò irin, ati idẹ. Arabinrin Tubali Kaini ni Naama.

Jẹnẹsisi 4

Jẹnẹsisi 4:21-23