Jẹnẹsisi 4:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ada ni ó bí Jabali, tíí ṣe baba ńlá gbogbo àwọn tí wọn ń gbé inú àgọ́, tí wọ́n sì ń sin ẹran ọ̀sìn.

Jẹnẹsisi 4

Jẹnẹsisi 4:15-26