Jẹnẹsisi 4:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti òní lọ, nígbà tí o bá dá oko, ilẹ̀ kò ní fi gbogbo agbára rẹ̀ so èso fún ọ mọ́, ìsáǹsá ati alárìnká ni o óo sì jẹ́ lórí ilẹ̀ ayé.”

Jẹnẹsisi 4

Jẹnẹsisi 4:6-19