Jẹnẹsisi 39:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Pọtifari ti fi Josẹfu ṣe alabojuto ilé rẹ̀ ati gbogbo ohun ìní rẹ̀, OLUWA bẹ̀rẹ̀ sí bukun ìdílé Pọtifari, ará Ijipti náà, ati ohun gbogbo tí ó ní nítorí ti Josẹfu.

Jẹnẹsisi 39

Jẹnẹsisi 39:1-8