Jẹnẹsisi 39:20 BIBELI MIMỌ (BM)

ó sì sọ Josẹfu sinu ọgbà ẹ̀wọ̀n. Ibi tí wọn ń ti àwọn tí ọba bá sọ sí ẹ̀wọ̀n mọ́ ni wọ́n tì í mọ́.

Jẹnẹsisi 39

Jẹnẹsisi 39:11-23