Jẹnẹsisi 39:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó dé, obinrin yìí sọ ohun kan náà fún un, ó ní, “Ẹrú ará Heberu tí o mú wá sí ààrin wa, ni ó déédé wọlé tọ̀ mí wá láti fi ẹ̀gbin lọ̀ mí,

Jẹnẹsisi 39

Jẹnẹsisi 39:15-23