Jẹnẹsisi 39:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ní ọjọ́ kan nígbà tí Josẹfu wọ inú ilé lọ láti ṣe iṣẹ́ rẹ̀, kò sí ẹnikẹ́ni nílé ninu àwọn ọkunrin tí wọn ń ṣiṣẹ́ níbẹ̀.

Jẹnẹsisi 39

Jẹnẹsisi 39:10-16