Jẹnẹsisi 38:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò pẹ́ pupọ lẹ́yìn náà ni Juda bá fi àwọn arakunrin rẹ̀ sílẹ̀, ó kó lọ sí ọ̀dọ̀ ará Adulamu kan tí wọn ń pè ní Hira.

Jẹnẹsisi 38

Jẹnẹsisi 38:1-3