Jẹnẹsisi 37:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi pẹlu yín, a wà ní oko ní ọjọ́ kan, à ń di ìtí ọkà, mo rí i tí ìtí ọkà tèmi wà lóòró, ó dúró ṣánṣán, àwọn ìtí ọkà tiyín sì yí i ká, wọ́n ń foríbalẹ̀ fún un.”

Jẹnẹsisi 37

Jẹnẹsisi 37:4-9