Jẹnẹsisi 37:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Israẹli fẹ́ràn Josẹfu ju gbogbo àwọn ọmọ rẹ̀ yòókù lọ, nítorí pé ó ti di arúgbó kí ó tó bí i, nítorí náà ó dá ẹ̀wù aláràbarà kan fún un.

Jẹnẹsisi 37

Jẹnẹsisi 37:1-9