Jẹnẹsisi 37:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Reubẹni pada dé ibi kànga gbígbẹ tí wọ́n ju Josẹfu sí, tí ó rí i pé kò sí níbẹ̀ mọ́, ó fa aṣọ rẹ̀ ya láti fi ìbànújẹ́ rẹ̀ hàn.

Jẹnẹsisi 37

Jẹnẹsisi 37:27-36