Jẹnẹsisi 37:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Juda bá sọ fún àwọn arakunrin rẹ̀, ó ní, “Anfaani wo ni yóo jẹ́ fún wa bí a bá pa arakunrin wa, tí a sì bo ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀?

Jẹnẹsisi 37

Jẹnẹsisi 37:21-34