Jẹnẹsisi 37:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Josẹfu ti dé ọ̀dọ̀ àwọn arakunrin rẹ̀, wọ́n fi ipá bọ́ ẹ̀wù aláràbarà rẹ̀ lọ́rùn rẹ̀,

Jẹnẹsisi 37

Jẹnẹsisi 37:13-25