Jẹnẹsisi 37:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á pa á, kí á wọ́ ọ sinu kòtò kan, kí á sọ pé ẹranko burúkú kan ni ó pa á jẹ, kí á wá wò ó bí àlá rẹ̀ yóo ṣe ṣẹ.”

Jẹnẹsisi 37

Jẹnẹsisi 37:15-25