Jẹnẹsisi 37:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti rí i tí ó yọ lókèèrè, kí ó tilẹ̀ tó súnmọ́ ọ̀dọ̀ wọn, wọ́n dìtẹ̀ mọ́ ọn láti pa á.

Jẹnẹsisi 37

Jẹnẹsisi 37:15-24