Jẹnẹsisi 37:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Israẹli bá pe Josẹfu, ó ní, “Ǹjẹ́ Ṣekemu kọ́ ni àwọn arakunrin rẹ da ẹran lọ? Wò ó, wá kí n rán ọ sí wọn.” Josẹfu bá dáhùn pé, “Èmi nìyí.”

Jẹnẹsisi 37

Jẹnẹsisi 37:3-16