Jẹnẹsisi 37:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn arakunrin rẹ̀ bá bẹ̀rẹ̀ sí ṣe ìlara rẹ̀, ṣugbọn baba rẹ̀ kò gbàgbé ọ̀rọ̀ náà, ó ń rò ó ní ọkàn rẹ̀.

Jẹnẹsisi 37

Jẹnẹsisi 37:10-18