Jẹnẹsisi 36:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí ni pé ọrọ̀ wọn ti pọ̀ ju kí wọ́n jọ máa gbé pọ̀ lọ, ilẹ̀ tí wọ́n sì ti ń ṣe àtìpó kò gbà wọ́n mọ́, nítorí pé wọ́n ní ẹran ọ̀sìn tí ó pọ̀.

Jẹnẹsisi 36

Jẹnẹsisi 36:4-17