Jẹnẹsisi 36:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Oholibama bí Jeuṣi, Jalamu ati Kora. Àwọn ni ọmọ Esau, tí àwọn aya rẹ̀ bí fún un ní ilẹ̀ Kenaani.

Jẹnẹsisi 36

Jẹnẹsisi 36:3-12