Jẹnẹsisi 36:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Magidieli ati Iramu. Àwọn ni ìjòyè ní Edomu, gẹ́gẹ́ bí ìlú wọn ní ilẹ̀ ìní wọn, Esau tí àdàpè rẹ̀ ń jẹ́ Edomu sì ni baba àwọn ará Edomu.

Jẹnẹsisi 36

Jẹnẹsisi 36:35-43