Jẹnẹsisi 36:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Orúkọ àwọn ìjòyè tí wọ́n ṣẹ̀ lára Esau nìwọ̀nyí, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn ati ìlú tí olukuluku ti jọba: Timna, Alfa, Jeteti,

Jẹnẹsisi 36

Jẹnẹsisi 36:38-43