Jẹnẹsisi 36:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Huṣamu kú, Hadadi, ọmọ Bedadi, tí ó ṣẹgun Midiani, ní ilẹ̀ Moabu gorí oyè, orúkọ ìlú tirẹ̀ ni Afiti.

Jẹnẹsisi 36

Jẹnẹsisi 36:33-42