Jẹnẹsisi 36:25-29 BIBELI MIMỌ (BM)

25. Àwọn ọmọ Ana ni, Diṣoni ati Oholibama.

26. Àwọn ọmọ Diṣoni ni Hemdani, Eṣibani, Itirani, ati Kerani.

27. Àwọn ọmọ Eseri ni: Bilihani, Saafani, ati Akani.

28. Àwọn ọmọ Diṣani ni: Usi ati Arani.

29. Àwọn ìjòyè tí wọ́n ṣẹ̀ lára Hori nìwọ̀nyí: Lotani, Ṣobali, Sibeoni,

Jẹnẹsisi 36