Jẹnẹsisi 36:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu àwọn ọmọbinrin Kenaani ni Esau ti fẹ́ aya, ekinni ń jẹ́ Ada, ọmọ Eloni ará Hiti, ekeji ń jẹ́ Oholibama, ọmọ Ana tí baba rẹ̀ ń jẹ́ Sibeoni, ará Hifi.

Jẹnẹsisi 36

Jẹnẹsisi 36:1-3