Jẹnẹsisi 36:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Lára àwọn ọmọ Oholibama, aya Esau: àwọn tí wọ́n jẹ́ ìjòyè ni: Jeuṣi, Jalamu, ati Kora. Àwọn ni ìjòyè tí wọ́n ṣẹ̀ láti ọ̀dọ̀ Oholibama, ọmọ Ana, aya Esau.

Jẹnẹsisi 36

Jẹnẹsisi 36:9-23