Jẹnẹsisi 36:12 BIBELI MIMỌ (BM)

(Elifasi, ọmọ Esau ní obinrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Timna, òun ni ó bí Amaleki fún un.) Àwọn ni àwọn ọmọ Ada, aya Esau.

Jẹnẹsisi 36

Jẹnẹsisi 36:2-14