Jẹnẹsisi 35:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Jakọbu jẹ́ mejila. Àwọn tí Lea bí ni: Reubẹni, àkọ́bí Jakọbu. Lẹ́hìn rẹ̀ ni ó bí Simeoni, Lefi, Juda, Isakari ati Sebuluni.

Jẹnẹsisi 35

Jẹnẹsisi 35:18-27