Jẹnẹsisi 35:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ẹ̀mí rẹ̀ ń bọ́ lọ, kí ó tó kú, ó sọ ọmọ náà ní Benoni, ṣugbọn baba rẹ̀ sọ ọ́ ní Bẹnjamini.

Jẹnẹsisi 35

Jẹnẹsisi 35:16-19