Jẹnẹsisi 35:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu gbé ọ̀wọ̀n òkúta kan nàró níbẹ̀, ó fi ohun mímu rúbọ lórí òkúta náà, ó ta òróró sórí rẹ̀,

Jẹnẹsisi 35

Jẹnẹsisi 35:5-22