Jẹnẹsisi 35:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, Ọlọrun sọ fún Jakọbu pé, “Dìde, lọ sí Bẹtẹli kí o máa gbé ibẹ̀, kí o tẹ́ pẹpẹ kan fún Ọlọrun tí ó farahàn ọ́ nígbà tí ò ń sálọ fún Esau, arakunrin rẹ.”

Jẹnẹsisi 35

Jẹnẹsisi 35:1-7