Jẹnẹsisi 34:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Hamori bá wọn sọ̀rọ̀, ó ní, “Ọkàn Ṣekemu, ọmọ mi, fà sí arabinrin yín, ẹ jọ̀wọ́, ẹ fún un kí ó fi ṣe aya.

Jẹnẹsisi 34

Jẹnẹsisi 34:1-11