Jẹnẹsisi 34:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu ti gbọ́ pé ó ti ba Dina, ọmọ rẹ̀ jẹ́, ṣugbọn àwọn ọmọ rẹ̀ wà pẹlu àwọn ẹran ninu pápá, Jakọbu kò sọ nǹkankan títí tí wọ́n fi dé.

Jẹnẹsisi 34

Jẹnẹsisi 34:1-6