Jẹnẹsisi 34:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kẹta, nígbà tí ará kan wọ́n, meji ninu àwọn ọmọ Jakọbu, Simeoni ati Lefi, arakunrin Dina, mú idà wọn, wọ́n jálu àwọn ará ìlú náà lójijì, wọ́n sì pa gbogbo ọkunrin wọn.

Jẹnẹsisi 34

Jẹnẹsisi 34:22-27