Jẹnẹsisi 34:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun kan ṣoṣo ni wọ́n ní kí á ṣe kí á lè jọ máa gbé pọ̀, kí á sì di ọ̀kan, wọ́n ní olukuluku ọkunrin wa gbọdọ̀ kọlà abẹ́ gẹ́gẹ́ bíi tiwọn.

Jẹnẹsisi 34

Jẹnẹsisi 34:13-23