Jẹnẹsisi 34:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọdọmọkunrin náà kò fi ọ̀rọ̀ náà falẹ̀, nítorí pé ó fẹ́ràn ọmọbinrin Jakọbu lọpọlọpọ. Ninu gbogbo ìdílé ọmọkunrin yìí, òun ni ó jẹ́ eniyan pataki jùlọ.

Jẹnẹsisi 34

Jẹnẹsisi 34:18-21