Jẹnẹsisi 34:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ẹ bá kọ̀, tí ẹ kò gbà láti kọlà abẹ́, a óo mú ọmọbinrin wa, a óo sì máa lọ.”

Jẹnẹsisi 34

Jẹnẹsisi 34:10-23