Jẹnẹsisi 34:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọgbọ́n ẹ̀tàn ni àwọn ọmọ Jakọbu fi dá Ṣekemu ati Hamori, baba rẹ̀ lóhùn, nítorí bíbà tí ó ba Dina, arabinrin wọn jẹ́.

Jẹnẹsisi 34

Jẹnẹsisi 34:7-18