Jẹnẹsisi 34:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣekemu tún wí fún baba ati àwọn arakunrin omidan náà pé, “Ẹ jọ̀wọ́, ẹ yọ́nú sí mi, ohunkohun tí ẹ bá ní kí n san, n óo san án.

Jẹnẹsisi 34

Jẹnẹsisi 34:1-18