Jẹnẹsisi 33:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Lea ati àwọn ọmọ rẹ̀ náà súnmọ́ wọn, àwọn náà wólẹ̀ fún un, lẹ́yìn náà ni Josẹfu ati Rakẹli súnmọ́ ọn, àwọn náà wólẹ̀ fún un bákan náà.

Jẹnẹsisi 33

Jẹnẹsisi 33:3-10