Jẹnẹsisi 33:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Oluwa mi, máa lọ níwájú, n óo máa bọ̀ pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ níwọ̀n bí ìrìn àwọn ẹran ati àwọn ọmọ bá ti lè yá mọ, títí tí n óo fi wá bá oluwa mi ní Seiri.”

Jẹnẹsisi 33

Jẹnẹsisi 33:9-15