Jẹnẹsisi 32:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní òru ọjọ́ náà gan an, ó dìde ó kó àwọn aya rẹ̀ mejeeji, àwọn iranṣẹbinrin mejeeji ati àwọn ọmọ rẹ̀ mọkọọkanla, ó kọjá sí ìhà keji odò Jaboku.

Jẹnẹsisi 32

Jẹnẹsisi 32:12-29