Jẹnẹsisi 31:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wí fún wọn pé, “Mo ṣàkíyèsí pé baba yín kò fi ojurere wò mí bíi ti àtẹ̀yìnwá mọ́, ṣugbọn Ọlọrun baba mi wà pẹlu mi.

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:1-7