Jẹnẹsisi 31:48 BIBELI MIMỌ (BM)

Labani wí pé, “Òkítì yìí ni ohun ẹ̀rí láàrin èmi pẹlu rẹ lónìí.” Nítorí náà ó sọ ọ́ ní Galeedi.

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:43-52