Jẹnẹsisi 31:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sì sọ fún àwọn ìbátan rẹ̀ kí wọ́n kó òkúta jọ. Wọ́n sì kó òkúta jọ, wọ́n fi ṣe òkítì ńlá kan, gbogbo wọn bá jọ jẹun níbi òkítì náà.

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:44-55