Jẹnẹsisi 31:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni OLUWA sọ fún Jakọbu pé, “Pada lọ sí ilẹ̀ baba rẹ ati ti àwọn ìbátan rẹ, n óo sì wà pẹlu rẹ.”

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:1-7